NaijaMusic
9ice – Omo Olona
Omo Olona by 9ice Mp3 Download
Vibe to this track from 9ice tilted Omo Olona. Akande Abolore Adegbola Alexander Ajifolajifaola, better known as 9ice, is a Nigerian singer, songwriter and dancer. He is known for his powerful use of the Yoruba language in his music and his proverbial lyrics and unique style of delivery. It’s a track that speaks to the heart.
Use the link below to stream and download Omo Olona by 9ice.
Lyrics of Omo Olona by 9ice
Aitete mọna lo jẹ kọna jinỌmọ ọlọna, ọmọ ọlọnaFun mi lọna ki n maa lọAbeere ọna ki i ṣinaỌmọ ọlọna, ọmọ ọlọnaFun mi lọna ki n maa lọ
Ẹṣin to kọ sareNi gbogbo igba iran lọ maa wo kẹyinỌba ṣa laladeMo fori balẹJinwin-jinwin ilẹkẹ
University ti mi o lọỌrẹ mi to lọ ko ṣetanWọn ni n kọṣẹ, emi kọỌrẹ mi ti o kọ lo pawoGbọnmi si omi wọn o toLabalaba digbo lẹgunẸgun to gun mi, emi peregunMo parọda, mo siregun
Aitete mọna lo jẹ kọna jinỌmọ ọlọna, ọmọ ọlọnaFun mi lọna ki n maa lọAbeere ọna ki i ṣinaỌmọ ọlọna, ọmọ ọlọnaFun mi lọna ki n maa lọ
Ẹṣin to kọ sareNi gbogbo igba iran lọ maa wo kẹyinỌba ṣa laladeMo fori balẹJinwin-jinwin ilẹkẹ o
Nigba kan ri, mi o ṣe mu yanganWọn ni mama mi jami lẹnu ọyanJagidijagan pọKo ki n gbọ, ko ki n gbaA gba bọọlu a kan lẹsẹA kawe, kawe ori dọtaStill, a kere oko dele
Ah, igba tẹni to lọna deOun ta da’wọle yọri si rereO da bi ara loju ọmọ arayeEmi kọ, ọlọna lo n tọnaỌlọna lo n ṣ’ọnaOnile lo nileAlara gbayida, Baba miKabiesi o!
Ọlọna lo n tọnaAbeere ọna o ni ṣinaTo kọ sareIran lọ maa wo gbẹyinỌna ti mo tọ lo ṣamọna miỌba ṣa laladeJinwin-jinwin ilẹkẹ o
-
NaijaMusic8 months agoHuntrix – Golden (KPop Demon Hunters)
-
NaijaMusic7 months agoYaks Aruwa – Taimake Ni
-
NaijaMusic8 months agoThe Stranglers – Golden Brown (Slowed Down)
-
NaijaMusic7 months agoXania Monet – Let Go, Let God
-
NaijaMusic7 months agoGIMS – DO YOU LOVE ME
-
NaijaMusic6 months agoThrough Me – Lord I’M Tired But Don’T Give Up On Me