
Omo Olona by 9ice Mp3 Download
Vibe to this track from 9ice tilted Omo Olona. Akande Abolore Adegbola Alexander Ajifolajifaola, better known as 9ice, is a Nigerian singer, songwriter and dancer. He is known for his powerful use of the Yoruba language in his music and his proverbial lyrics and unique style of delivery. It’s a track that speaks to the heart.
Use the link below to stream and download Omo Olona by 9ice.
Lyrics of Omo Olona by 9ice
Aitete mọna lo jẹ kọna jin
Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna Fun mi lọna ki n maa lọ Abeere ọna ki i ṣina Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna Fun mi lọna ki n maa lọẸṣin to kọ sare
Ni gbogbo igba iran lọ maa wo kẹyin Ọba ṣa lalade Mo fori balẹ Jinwin-jinwin ilẹkẹUniversity ti mi o lọ
Ọrẹ mi to lọ ko ṣetan Wọn ni n kọṣẹ, emi kọ Ọrẹ mi ti o kọ lo pawo Gbọnmi si omi wọn o to Labalaba digbo lẹgun Ẹgun to gun mi, emi peregun Mo parọda, mo siregunAitete mọna lo jẹ kọna jin
Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna Fun mi lọna ki n maa lọ Abeere ọna ki i ṣina Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna Fun mi lọna ki n maa lọẸṣin to kọ sare
Ni gbogbo igba iran lọ maa wo kẹyin Ọba ṣa lalade Mo fori balẹ Jinwin-jinwin ilẹkẹ oNigba kan ri, mi o ṣe mu yangan
Wọn ni mama mi jami lẹnu ọyan Jagidijagan pọ Ko ki n gbọ, ko ki n gba A gba bọọlu a kan lẹsẹ A kawe, kawe ori dọta Still, a kere oko deleAh, igba tẹni to lọna de
Oun ta da’wọle yọri si rere O da bi ara loju ọmọ araye Emi kọ, ọlọna lo n tọna Ọlọna lo n ṣ’ọna Onile lo nile Alara gbayida, Baba mi Kabiesi o!Ọlọna lo n tọna
Abeere ọna o ni ṣina To kọ sare Iran lọ maa wo gbẹyin Ọna ti mo tọ lo ṣamọna mi Ọba ṣa lalade Jinwin-jinwin ilẹkẹ o
Leave a Reply