
Gbajumo by 9ice Mp3 Download
Vibe to this track from 9ice tilted Gbajumo. Akande Abolore Adegbola Alexander Ajifolajifaola, better known as 9ice, is a Nigerian singer, songwriter and dancer. He is known for his powerful use of the Yoruba language in his music and his proverbial lyrics and unique style of delivery. It’s a track that speaks to the heart.
Use the link below to stream and download Gbajumo by 9ice.
Lyrics of Gbajumo by 9ice
Say it again
And say it againA o ṣ’oro, a o ṣ’oro (a o ṣ’oro, a o ṣ’oro)
Ikoko aje to kun f’omi Ma ri bu, ma wẹ Ko mu ire ko wa o (won’t you say it for me, for me o?) Ti ire ba de, ma rẹrin ayọ (won’t you say it for me, for me o?) Tori mo ko’re lọnaKi i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti Ki i ṣe nnkan ti Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti Ki i ṣe nnkan ti Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti Gbajumọ, o ya, ṣe ẹẹkan si oKaka ki
Kaka ki gbajumọ mi j’ọpọlọ o Ẹni maa gba kọnkọ fun a jade Ọṣunrin lo gbayi ju ninu igi Ọkin lo gbayi ju ninu ẹyẹ Ogbomu lo gbayi ju ninu ewe Ọba lo gbayi ju ninu eeyanKaka ki
Ki n ma gbayi nile, loko Ọmọ ẹru a jọba, ile a fojuro Baba, baba, baba I go dey busy spending money Making money pieces I go dey busy spending money Make money like pieces (pieces) A o ṣ’oro, a o ṣ’oro (say it again) Ikoko aje to kun f’omi Ma ri bu, ma wẹ Ko mu ire ko wa o (won’t you say it for me, for me o?) Ti ire ba de, ma rẹrin ayọ (won’t you say it for me, for me o?) Tori mo ko’re lọnaKi i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti Ki i ṣe nnkan ti Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti Ki i ṣe nnkan ti Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti Gbajumọ, o ya, ṣe ẹẹkan si oṢ’owo ni? Ṣ’owo?
Ṣ’owo ni? Ṣ’owo? Money na paper, fi ran mi (It’s Bizzle on the mix) O pọ, ṣ’owo ni? Ṣ’owo? Ṣ’owo ni? Ṣ’owo? Money na paper, fi ran mi
Leave a Reply