King Sunny Adé – Ara Ma Nfe Sinmi

Ara Ma Nfe Sinmi by King Sunny Adé Mp3 Download

The new King Sunny Adé track titled Ara Ma Nfe Sinmi. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. This is what real music feels like.

          DOWNLOAD MUSIC HERE

Use the link below to stream and download Ara Ma Nfe Sinmi by King Sunny Adé.

Lyrics of Ara Ma Nfe Sinmi by King Sunny Adé

Ọrẹ rẹ die bínú bínú woni mo kuIya gbó ni lè ebi ń wá ní kiriIya gbó ni lè ọrẹ ń wá ní kiriTebi Tara tore, won temi lagoLai mo wípéMi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn loMi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn loOtoto larin wá, Ototo larin wáṢebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara waỌrẹ wá, ọjọ’ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinnaọjọ’ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinnaÌkà eda tó fowo padà Ọlọ’run lojuÌkà eda tó fowo padà Ọlọ’run lojuÌdájọ’ ó jìnnà, idajo ó jìnnàAye ẹ má dalekunTorí mi ò báwọn wá, èmi ò ní báwọn loMi ò báwọn wá, èmi ó ní báwọn loTorí, òtoto larin wa, òtoto larin wáṢebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara waAyéeeeeeee, Ayee yiii ooooAyéeeeeeee, Ayee yiii ooooAyé totoỌjọ’ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó ooỌjọ’ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó ooỌjọ’ ó rò se, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó ooAra máa ń fẹ’, (ara máa ń fẹ’ simi)E rọra ṣe (ara máa ń fẹ’ simi)E rọra (ara máa ń fẹ’ simi)Ara máa ń fẹẹ (ara máa ń fẹ’ simi)Àní ara máa ń fẹ’ ó jare (ara máa ń fẹ’ simi)Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi)Ọrẹ wá jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi)Ifakafiki làálàá lè (ara máa ń fẹ’ simi)Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi)Ará máa ń fẹ’ ó jare (ara máa ń fẹ’ simi)Ifakafiki lórí ẹni (ara máa ń fẹ’ simi)Ará máa ń fẹ’ (ara máa ń fẹ’ simi)(End.)

Download Mp3 Here

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*