King Sunny Adé – Mo Beru Agba

Mo Beru Agba by King Sunny Adé Mp3 Download

The new King Sunny Adé track titled Mo Beru Agba. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. This is what real music feels like.

          DOWNLOAD MUSIC HERE

Use the link below to stream and download Mo Beru Agba by King Sunny Adé.

Lyrics of Mo Beru Agba by King Sunny Adé

Mo beru aagba (mo beru agba, mo beru agba o)
A i beru agba ni o jaiye o gunElegbe moni mo beru agbaAgba n’bowa kan e o eeAgba n’bowa kan e o o laiye nbiAgba n’bowa kan e o eAye o o o (Aye o Aye o e)
Oṣika, ranti ojo atisun re o eIwo odale, ranti ojo atisun re o eEni s’ebi (ibi lo mi a j’ere fun)Eni ba se ka nko oIka lo mi a j’ere funBo ba wun e ko s’ereIre lo mi a j’ere reBo wun e ko se kaIka lo mi a j’ere re
Bofe bofeEsan a ke lori eBode bofeEsan a ke lori eOdale se o ngbo (esan a ke lori re)
Nje mo d’ifa titi mo mu re ko ifaNo da da mo mu re ‘di opeNje mo d’ifa titi mo mu re ko ifaNo da da mo mu re ‘di opeOpe mi ti ti mo se b’ojo lo roOjo pami lapa kan lapa kan miOjo pa mi o mase p’oremi
Ah agbo ‘ba mi digi ogiTio loko tioloAgbo ‘ba mi digi ogiTio loko tioloRasaki ijo ti ya oTio loko tioloAgbo ‘ba mi digi ogiTio loko tiolo
 

Download Mp3 Here

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*