
Stubborn by Portable Mp3 Download
Listen to this banger by Portable tilted Stubborn. Habeeb Okikiola Badmus popularly known as Portable is a Nigerian singer, songwriter and rapper. He is known for controversies and online buzz. Add it to your rotation if you love chill, quality sounds.
Use the link below to stream and download Stubborn by Portable.
Lyrics of Stubborn by Portable
Ìlera l’ọrọ o
Owó lo ma ń calm stubborn Ìlera l’ọrọ o Para o, stubborn Ẹ yé ma f’ọmọ we ọmọ o (Xtra Pro) Ọmọ Ọlalomi again o Dem call me Portable Baby, ohWọn ni ko s’àyè loke o
O wa àyè fun mi ni bẹ o O gb’ógo wálẹ Ìyanu l’orúkọ rẹ o Wọn ni, “Ko s’àyè loke o” O wa àyè fun mi ni bẹ o O gb’ógo fun ọlẹ Ìyanu l’orúkọ rẹMo ti kọ hundred million fun Abu Abel
Mo ni ko ba mi kọle Oluwa lo lowo, Oluwa lo nilẹ Ẹsi ma ba mi s’ile o Wọ́n si ma ba ẹ ṣ’ile Èmi a ba ‘wọ́ ṣ’ile o Ìwọ a ba mi ṣ’ile o Ọla ń ṣ’ilè oC.E.O, eèyan DPO
Èeyan to ni record label o Zeh Nation lo ń gbé mi de bẹ o Ọla ṣ’ile oÌlera l’ọrọ o
Owó lo ma ń calm stubborn Ìlera l’ọrọ o Para o, stubborn Ẹ yé ma f’ọmọ we ọmọ o Wọn tí gé etí mí lọ, mi ò gbọnrán ó O to lẹ o, o to òkè ó Ọmọ ológo o wa lẹ o Ojo gẹ óWọn ni, “ko s’àyè loke o”
O wa àyè funmi ni bẹ o O gb’ógo wa’lẹ Ìyanu l’orúkọ rẹ o Wọn ni, “Ko s’àyè loke o” O wa àyè funmi ni bẹ o O gb’ógo fún ọlẹ Ìyanu l’oruko rẹC.E.O, eèyan DPO
Èyan to ni record label o Zeh Nation lo ń gbé mi de bẹ o Ọla ṣ’ilè oIlera l’ọrọ o, owo lo ma ń calm stubborn
Para o, stubborn o Mo ni, “Ẹ ye ma f’ọmọ we ọmọ o” Mi o gbọran o (Black smith shit tinish polo bla)
Leave a Reply