
Yes And Amen by Tope Alabi Mp3 Download
New sounds by Tope Alabi just landed titled Yes And Amen. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu. Music lovers, don’t miss this beautiful track.
Use the link below to stream and download Yes And Amen by Tope Alabi.
Lyrics of Yes And Amen by Tope Alabi
Amin ase ida a lamo o
Eni ti o ni a padanu Iba o to to olu Imo o Eni ti o ni o, ko ni nkankan o Amin asedaEni ti o ni o, ko ni nkankan o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (ko ni nkankan) Eni ti o ni o, ko ni nkankan o Eni ti o ni o, ko ni nkankan E ko ni nkankan oMo wa ri foba to ni di da aiye
Ibare mare e, oni gbede orun Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo Bo ti doyi kato Iba oni mo to ga ju, eh-eh Baba ni baba se Amin ase ida mo gbe ba fun Amin ase ida la mo oEni ti o ni o ke, eni ti o ni a padanu, adanu nla lo pa laye, lorun
Iba o toto olu imo A ton ton to, mo ri ba, mori ba o Eni ti o ni o ko ni nkankan, ko ni nkankan Eni ti o ni o ko ni nkankan o E ma ni penre labo, eni ti o ni o, ko ni nkankan Ko ni kini nkan lagbon, eni ti o ni o, ko ni nkankan o O tan fun laiye lorun o, eni ti o ni oKo ni nkankan, o da okun, O da oosa
Alara to fi omi se osho, iwo to mo ibi eja gba do odo Majemu to bu ko ja okun Iyanrin te ka aiye, o da okunkun biri mu Oga imole, oju orun o ni ilekun o Ogbe bi mejeeji, lai rin irin ajo, o mu eda gba inu eda waiye Ibi emi ngba lo ba, eni kan o mo, ajulo o, eni ti o wa o Ko le mo nkankan, eni ti o wa ke oEni ti o ni o, ko ni nkankan o
Ko ri nkankan o o Eni ti o ni o, ko ni nkankan Afoju san ju oni to hun lo mo gba Eni ti o ni o (e-e), ko ni nkankan, ko ni nkankan Eni ti o ni o (e-e), ko ni nkankanMajemu alai lepin n lo je, ijinle alaile tun wo
Irawo nyo lailai lo nka beni, osupa nse atokun to ba dale beni o Ibi gbogbo la n ti mi ri beni, o to lo fara da orun saiye beni o O se ojo otun so da eran beni Osuwon bi oye, otun sotutu beni o Eranko Igbo won lo su a beni Eweko, ewebe igi iyen o se sawa ri naEni ti o ri se e, ko ri nkankan o
Eni ti o ri se e, ko ri nkan Eni ti o ri se e, ko ri nkankan Ko da ko ri ra e pa be ni Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o-o Eni ti o ri se e, ko ri nkankanOse mi da bi ohun, opin mi ni ipin, ti ko Jo ti eni keji
Mi o la le hu, emi ni ami aseda latorun Adagbeyin ni mi o wa fi mi joba Ohun gbogbo ti o ti ko da, odami ofunmi ni re Emi ni beeni, ase olodumare ni, amin lohun, emi lami Ayanmo ogo, ogun mi ni Eda emi lo fi se ranse mi Akori Iran mi, oju ogo re niMo ni imi ye re ninu
Eni o ri mi, ko ri nkankan e, eni ti o ri mi Ko ri nkankan, eni ti o ri mi e Ko ri se olorun wo e, eni ti o ri mi ke, ko ri nkan Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o, e o foju Eni ti o ri mi, ko ri se Olorun wo Ko ri Olodumare, oda mi bi ohun ni Eni ti o ri mi, ko ri nkankanEni ti o ri mi, ko ri se Olorun wo, o
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o Eni ti o ri mi, eni ti o ri mi, ko ri se Olorun, eni ti o ri pa, aje ko ri nkankan Eni ti o ri mi ko ri nkankanAmi lawa je, si iwo amin
Beni ire loje ki aiye wa oOlorun la min
Amin lon famin wa han Aiye, atorun lamin yen o Aseda ni amin Oro re lo je ki a ma wa Olorun lamin, Olorun laminTo ba se amin, Olorun lo se (amin, amin, amin), to ba so pe amin Olorun (amin)
Amin Olorun ni (amin), amin ori wa, amin irin ajo (amin), amin ati waye Amin ati gbe aye (amin), amin ati pada, amin gbogbo e (amin), amin ati ye e (amin) Amin ati se rere (amin), amin ati goke (amin), amin ati bo lowo ogun (amin) Amin ati di eni nla (amin), amin lami ori wa (amin), ese amin o, amin Amin loruko re aseda (amin), amin loruko re aseda (amin) Amin ni mo se kemi bale ye (amin), amin ni mo se kin le goke (amin) Amin ni mo se kappa ota ma kami (amin), amin ni mo se kin le din la (amin) Amin ni mo se kin le pada (amin), amin ni mo se kin le ba joba (amin) Amin ni mo se si Olodumare (amin), mo sope yes, mo sope amen (amin), mo sope yes, mo sope amen
Leave a Reply