Yinka Ayefele – Next Level Praise

Next Level Praise by Yinka Ayefele Mp3 Download

Track alert Yinka Ayefele brings a vibe you’ll love titled Next Level Praise. Yinka Ayefele is a Nigerian gospel musician, singer, songwriter, and media entrepreneur. Born Olayinka Joel Ayefele in Ipoti-Ekiti, Ekiti State, Nigeria, in 1968. Add this gem to your playlist if you love great vibes.

          DOWNLOAD MUSIC HERE

Simply use the link below to stream and download Next Level Praise by Yinka Ayefele.

Lyrics of Next Level Praise by Yinka Ayefele

Iyin ati ope loye fun babaIyin ati ope fun messiahOba ti o pa wa mo ninu ewuIyin ati ope fun JehovahBi mo ba lawo ti o po to one thousandKo ti e le to lati yin ooooAgaba igbega ti mo wa yii ni next levelIyin ati ope fun Jah JehovahIyin, ogo ye ooModupe o baba mi ogo ye oEmi ti won ko bata fi ra atupa lo jo siMo wa di eni ajitona fun araye o waSo mi di ayan mo wa di ayan oloyimomoOro mi di ijoOro mi dijo e wa bamiyo eba mi dupeEwabamiyo loni aye ye miMoroju rere olorun ogo ye o ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomoBi edumare ba le se se ti mo dide ri n gbogbo aye yin yio bami fiIyin fi ijo yin baba jake jado agbaye okiki a kan je ko sese daaboboMi o awon toku to n ba binu je ki inu won ro,Je ki inu won ro ki a le fi idunnu jaye pe bi won ba wa ko wipe awonO gba wa se won mose fi won se sample iya ki won le mo pe iwo lo ObaBi mo ba se re lowo,Ayefele bi mo ba gbo ilu bi mo ba ri ilu inu mi a dunAra mi a ya gaga ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomoBa se lu lu yi bi e se n jo iku o niPawa o aarun o ni se yin o ka jo ma se pepepeAyefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomoHypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo naPa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupoHypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ceOjo ti o ro ti o kun ikoko ni agbala ojo oun lo ro sinu apere ti koDe kun so ikoko wa yo wipe apere o le mu ojo dani e bami so fun ikokoKi ikoko mama yo mo asiko n bo wa fun apere bi ojo ba da tan apere nBo wa ko ore oko bi ojo ba ti da igba eda asiko eda wa lowo babaOke pa ironu ti ore asiko re bo waDe pa ironu ti o ya bere mo le si joAyefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomoHypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo naPa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupoHypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ceTi o ba rii se ma se pe padii e lo le because onitiri ola tun leSaalaye be e mo ko si owo loni owo n bo bi o dola ko si ola loni olaN bo bo dola agan mama beru mo omo n bo wa asiko eda igba eda wa lowoBaba oke then ironu pupo hypertension ma deLo tun fa wa pa ironu oya bere mo le si ijoAyefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomoHypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo naPa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupoHypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ceBe emi ko olorun mi o ori mo mu waye ori owo ni ori mo.Mu wa ye oriola ni agbon ti o ni omi ninu ko si eni ti o mo idi re

Download Mp3 Here

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*