
Omode O Mela by King Sunny Adé Mp3 Download
The new King Sunny Adé track titled Omode O Mela. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. This is what real music feels like.
Use the link below to stream and download Omode O Mela by King Sunny Adé.
Lyrics of Omode O Mela by King Sunny Adé
Wọni ọmọde o Mela
Olohun Mela katakata Wọni ọmọde o Mela Olohun Mela katakata Lai Mope èlà katakata ọba ija niOre, kaso aja mole, kaso ẹkun mole
Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọlá Koye won rara bwag eyi ga Lọlá Koyewon raraỌlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi Sunny Ade ode bi otin déKaso aja mole, kaso ẹkun mole
Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọla Koyewon rara Eyi bu wa eyi ga lola Koyewon raraỌlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi Sunny Ade ode bi otin déỌpọlọ ye eyin o fi eyin pamo kilon fi pamo fún
Alangba yẹ eyin o fi pamo, kilon fi pamo fún Igun yẹ eyin, o fi eyin pamo, kilon fi pamo fún Igun ti o wa yẹ eyin to tun wa feyin pamoAti igun ati eyin rẹ, won o ṣe sebe je
Bi wọn ki wa gun lo
Bi wọn ki wa gun tete Bi wọn ki wa gun lo Bi wọn ki wa gun tete Iho iho ni akara wa ti moi moi ti n ṣe ogeEwé omo ogbon ṣe jube lo, omo logbe
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Ewé kín gbo Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Igba ti o ṣe tiwon, o sọ sí rárá Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Àwa ṣe tiwa won pon ju koko Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Ojú tó pọ koko kole tun lo sa morore Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Kingbo Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Ojumo
Leave a Reply