
Arugbo Ojo by David G Mp3 Download
You can’t skip this one from by David G’s music titled Arugbo Ojo. David Gbenga Olusegun, popularly known as “David G” is a Nigerian based Gospel artiste, a worship leader and a song writer. It’s a smooth and soulful ride you’ll want to replay.
Use the link below to stream and download Arugbo Ojo by David G.
Lyrics of Arugbo Ojo by David G
Edu mare Oba mi ni
Oba eh eh umm Mo wole fun o Alagbada ina Baba mi oo Mo wole fun o Ogbe nu wundia sododo Mo wole fun o Ato farati bi oke won ni Baba Mo wole fun o Arugbo Ojo Mo wole fun o Baba awon tio ni baba Ehh mo wole fun o Kabi O omasi o Baba mi Mo wole fun o Ogbe nu wundia sododo ododo Baba o Mo wole fun o Arugbo Ojo Ehh mo wole fun o mo wole fun o Baba oo mo wole fun o Ehh ehh Arugbo Ojo Arabaribitirabata Baba mi oo mo wole fun o Edumare Oba mo wole fun o mo wole fun o Oba lana Oba loni Baba mi Arugbo Ojo Mo wole fun o mo wole fun o mo wole fun o mo wole fun o Arugbo Ojo Oyigiyigi Alagbada Ina Oba wa mo wole fun o Baba wa ehh mo wole fun o mo wole fun oh oh mo wole fun o Arugbo OjoKabi O osi oh Baba
Alagbada Ina nio oo Baba Arugbo Ojo nio ooo Baba Baba awon ti ko ni baba Emi Mimo ma nio o Baba Mimo Mimo ma nio o Baba mi Eru jeje nio Oluwa Oba Arugbo OjoBaba mi nio ooo Baba
Eleda mi nio Baba Atorise nio oo Baba mi Ataye se nio oo Baba Ehh Atowo se ma nio oo Baba Oloju Ina nio oo Baba mi Emi mimo nio ooo Arugbo Ojo Arugbo Ojo nio oo Baba Kinihun eya Judah nio oo BabaEhh mo wole fun o
Arugbo Arugbo Ojo Mo wole fun o ehh mo wole fun o mo wole fun o Arugbo ojo Ehh yea mo wole fun o mo wole fun o Baba mi mo wole fun o Opa Mose Arugbo ojo Arabaribiti Baba mi o mo wole fun o ohoh mo wole fun o mo wole mo wole fun o Arugbo ojo Arugbo ojo Eyin L’Atorise mo wole fun o Eyin L’Atumise mo wole fun o Eyin L’Atunwase mo ma wole fun o Eyin Lameda Awoeda oo Arugbo Ojo Eyin La Arugbo Ojo Ope lo pe re oh Baba Ola lo’la Re O Oba mo wole fun o Iyin ni mo fun o Baba mi Atobajaiye mo wole fun o Mo wole fun oo Mo wole fun oo oh oh
Leave a Reply