Kizz Daniel – Showa

Showa by Kizz Daniel Mp3 Download

Hear the latest fire from Kizz Daniel tilted Showa. Oluwatobiloba Daniel Anidugbe, better known as Kizz Daniel, is a Nigerian singer and songwriter. He signed a record deal with G-Worldwide Entertainment in 2013. A strong addition to any music lover’s mix.

          DOWNLOAD MUSIC HERE

Use the link below to stream and download Showa by Kizz Daniel.

Lyrics of Showa by Kizz Daniel

Ahn-ahn
Alákọri, alakọkọ, ṣ’ómá fẹ mí? Ṣ’ómá là tán?Tí ń bà gbé wá (whoo), ṣ’ómá ká kọ?Ṣé mo máa ní problem pẹlú boys?Ta bà já, ká padà, má sá lọ CanadaIf I travel today, kí ń má bà ẹ l’ababa (l’ababa)Army man na my army manArmy man na my brother manÓ lè ní problem
Ahh, baby, ṣ’ówa pá oh? (Ṣ’ówá pá?)Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)Mo láyé lo máa jẹ kù oÌrù eléyìí ó mà ní problem (kan)Melanin poppin’, baby, nìṣó ní táBaby, sunshine give you filterOnidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu rarurábà
Ṣ’òní capital business? (Ṣ’owá?)Ṣ’òní character deaconess? (Ṣ’owá?)Can you wake up around 4:30 (ṣ’owá?)To make breakfast for me? (Ṣ’owá?)Tó bà dálẹ, ṣ’olè gimme-gimme? (Ṣ’owá?)Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ’owá?)Gimme-gimme, k’oma gbọn mi jigi (ṣ’owá?)Oh-ooh-oh
Long time ago, I say no kele fit make me conform, ooh-yahÒ ká mí mọ corner (ṣ’ó)Now, I won do am, now, I won run am (oya, uh)Very gentle girl (whoo)I’ll pick you up, turn you biggie girl (biggie girl)Mama say, “I don fall in love”And my papa say, “Ọmọ, jẹun lọ”
Ahh, baby, ṣ’ówa pá oh? (Ṣ’ówá pá?)Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)Mo láyé lo máa jẹ kù oÌrù eléyìí ó mà ní problem (kan)Melanin popping, baby, nìṣó ní táBaby, sunshine give you filterOnidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu, rarurábà
Ṣ’òní capital business? (Ṣ’owá?)Ṣ’òní character deaconess? (Ṣ’owá?)Can you wake up around 4:30 (ṣ’owá?)To make breakfast for me? (Ṣ’owá?)Tó bà dálẹ, ṣ’olè gimme-gimme? (Ṣ’owá?)Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ’owá?)Gimme-gimme, k’oma gbọn mi jigi (ṣ’owá?)Oh-ooh-oh
Oh-ooh-oh(Ṣ’owá?)(Ṣ’owá?)(Ṣ’owá?)(Ṣ’owá?) Oh-ooh-oh
 

Download Mp3 Here

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*