
Owereke by Bhadboi OML Mp3 Download
Discover the magic of Bhadboi OML’s music tilted Owereke. Akinyinka Kuham Oladimeji, widely recognised by his stage name Bhadboi OML, was born on February 19, 2000, in Mushin, Lagos. For those who live and breathe quality tunes.
Use the link below to stream and download Owereke by Bhadboi OML.
Lyrics of Owereke by Bhadboi OML
Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
Ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké) Eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) A ṣe Ọlọrun ló rán mi wá (ówéréké) Ó rán mi si Mushin, lọ si Ibadan (ówéréké) Ó rán mi si Ilé-Ife, yá l’Oshódi (ówéréké)Éwó ni ká ṣ’ore tán, káá dẹ di HOD (ówéréké)
Káá ṣ’ore tán, káá de tun lóṣó tii (ówéréké) Eh, ówéréké, igbayi lówó (ówéréké) Eh, ówéréké, igbayi lọlá (ówéréké) Ówéréké, igbayi t’ójó rọ (ówéréké) Igunnugun mi ó dẹ ni ku n léwé (ówéréké) Akalamagbó ó ni ku lóṣú mo oo (ówéréké) Eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)Ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ówéréké, kó si pressure, sẹ (ówéréké) Ówéréké, kó ni si wèrè mọ oo (ówéréké) Ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké) Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)Ah, ki lá mu wáiye? Aiyé lá má fii silẹ si
Tó difa fun ẹni tó bi’mọ, tó lo ji ‘rẹsi Ọga, go collect your two portion, k’ọn fi di ẹ sii Igbaju, igbamu pupọ, ni ti kẹri, kẹri Iyawó ẹnikan, aaṣọ mu ẹnikan Ẹnikán ó binu ẹnikan Ẹnikán ó dun bu ẹnikan Iyawo temi, aaṣọ mu ẹlomi To ba gbowo ẹlómi, a tun wa ji ówó temiÓwéréké, ówéréké oh (ówéréké)
Ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké) Eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) A ṣe Ọlọrun ló rán mi wá (ówéréké) Ó rán mi si Mushin, lọ si Ibadan (ówéréké) Ó rán mi si Ilé-Ifę, yá l’Oshódi (ówéréké)Éwó ni ká ṣ’ore tán, káá dẹ di HOD (ówéréké)
Káá ṣ’ore tán, káá de tun lóṣó tii (ówéréké) Eh, ówéréké, igbayi lówó (ówéréké) Eh, ówéréké, igbayi lọla (ówéréké) Ówéréké, igbayi t’ójó rọ (ówéréké) Igunnugun mi ó dẹ ni ku n léwé (ówéréké) Akalamagbó óni ku lóṣú mo oo (ówéréké) Eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)Ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ówéréké, ko si pressure, sẹ (ówéréké) Ówéréké, kó ni si wèrè mọ oo (ówéréké) Ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké) Ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké) Ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
Leave a Reply