
Ere by 9ice Mp3 Download
Vibe to this track from 9ice tilted Ere. Akande Abolore Adegbola Alexander Ajifolajifaola, better known as 9ice, is a Nigerian singer, songwriter and dancer. He is known for his powerful use of the Yoruba language in his music and his proverbial lyrics and unique style of delivery. It’s a track that speaks to the heart.
Use the link below to stream and download Ere by 9ice.
Lyrics of Ere by 9ice
Owo mo wa pa, mi o ba toṣí wa o
Ere mo wa ṣe, mi o ba tija wa o Enemies dey beside me, ṣugbọn, mi o ri wọn Wọn pariwo nita, ṣugbọn, mi o gbọ wọn Gbogbo aroye wọn ko ma ye miA o wa ṣere o (a o wa ṣere o)
A o wa ṣere o (a o wa ṣere o) Ọmọ ta gbe wa ko kekere o Ija lẹ ba wa, a o wa ṣere o (a o wa ṣere o) Mo ti pẹ n’ta tipẹ o (pẹ n’ta gan-an) Mo ti pẹ n’ta tipẹ o (pẹ n’ta gan-an ni)Mo ṣe ere ọmọde ti pe o (pẹ n’ta gan-an)
Mo ti daye tipẹ o Ẹ wa-wa, oh-oh Ẹ wa-wa, oh-oh Ẹ wa-wa, oh-ohEre mo wa ṣe, mi o ba tija wa o
Owo mo wa pa, mi o ba toṣí wa o Music in my vein, mi o ba tija wa o Music I dey play, mi o ba toṣi wa o Ẹ wa-wa, oh-oh (wa wo) Ẹ wa-wa, oh-oh (wa wo) Eh-eh, oh-ohEnemy, I go over them
Enemy, I go over- Enemy, I go over them Enemy, I go over- Enemy, I go over-Wọn petepero, over them
Petepero, see, I’m over them, yea Wọn lọ ile babalawo kan Emi gan babalawo kan nibi kan O lọ ile oniṣegun kan Emi gan-an wọn gbe iwe fun mi nibi kanAh! Emi ọmọ Ajibọla ọmọ Ẹdan
Ohun ta ba fọn fun fere yẹn ṣa lo maa fọn Gbọ na, this season o maa yatọ Faaji nisinyi, o kọ sisọ See many, many things la ti ṣe ri O ra Hennessy kan, o wa fẹ ma ba mi gbegbaI’m over them tipẹ-tipẹ ni
Mo ma ti mọ ìtọwo ibẹ tipẹ-tipẹ gan-an Me I ran all over them tipẹ-tipẹ Me, I just dey gboju n bẹ, emi ọmọ ọpẹI’m over them
Enemies, I’m over them Apetepero, over them still Adigun over them, babalawoGbese re o
Gbese re fun awọn ọta mi Gbese re o Gbese re fun awọn ẹni ibi Gbese re o Gbese re fun awọn ọta mi Gbese re o Gbese re fun awọn ẹni ibiYou are over them, Adigun
You be on them, Adigun (Nakhit) You are above them, Adigun o O ju wọn lọ, Adigun tipẹ-tipẹ (it’s Bizzle on the mix) Aro kese tipẹ-tipẹ Aro kese tipẹ-tipẹ (Opiro) Ọwọrin-ṣe-ogbe tipẹ-tipẹ
Leave a Reply