Portable – Stubborn

Stubborn by Portable Mp3 Download

Listen to this banger by Portable tilted Stubborn. Habeeb Okikiola Badmus popularly known as Portable is a Nigerian singer, songwriter and rapper. He is known for controversies and online buzz. Add it to your rotation if you love chill, quality sounds.

          DOWNLOAD MUSIC HERE

Use the link below to stream and download Stubborn by Portable.

Lyrics of Stubborn by Portable

Ìlera l’ọrọ oOwó lo ma ń calm stubbornÌlera l’ọrọ oPara o, stubbornẸ yé ma f’ọmọ we ọmọ o(Xtra Pro)Ọmọ Ọlalomi again oDem call me Portable Baby, oh
Wọn ni ko s’àyè loke oO wa àyè fun mi ni bẹ oO gb’ógo wálẹÌyanu l’orúkọ rẹ oWọn ni, “Ko s’àyè loke o”O wa àyè fun mi ni bẹ oO gb’ógo fun ọlẹÌyanu l’orúkọ rẹ
Mo ti kọ hundred million fun Abu AbelMo ni ko ba mi kọleOluwa lo lowo, Oluwa lo nilẹẸsi ma ba mi s’ile oWọ́n si ma ba ẹ ṣ’ileÈmi a ba ‘wọ́ ṣ’ile oÌwọ a ba mi ṣ’ile oỌla ń ṣ’ilè o
C.E.O, eèyan DPOÈeyan to ni record label oZeh Nation lo ń gbé mi de bẹ oỌla ṣ’ile o
Ìlera l’ọrọ oOwó lo ma ń calm stubbornÌlera l’ọrọ oPara o, stubbornẸ yé ma f’ọmọ we ọmọ oWọn tí gé etí mí lọ, mi ò gbọnrán óO to lẹ o, o to òkè óỌmọ ológo o wa lẹ oOjo gẹ ó
Wọn ni, “ko s’àyè loke o”O wa àyè funmi ni bẹ oO gb’ógo wa’lẹÌyanu l’orúkọ rẹ oWọn ni, “Ko s’àyè loke o”O wa àyè funmi ni bẹ oO gb’ógo fún ọlẹÌyanu l’oruko rẹ
C.E.O, eèyan DPOÈyan to ni record label oZeh Nation lo ń gbé mi de bẹ oỌla ṣ’ilè o
Ilera l’ọrọ o, owo lo ma ń calm stubbornPara o, stubborn oMo ni, “Ẹ ye ma f’ọmọ we ọmọ o”Mi o gbọran o(Black smith shit tinish polo bla)
 

Download Mp3 Here

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*