
Alagbara Giga by Bidemi Olaoba Mp3 Download
Fuel your day with Bidemi Olaoba’s music titled Alagbara Giga. AbAkinola Ayoola Michael also known as Alayo Melody Singer is a Nigerian gospel juju Tungba musician and a songwriter. He was born in Lagos, lives in Abeokuta. For those who live and breathe quality tunes.
Use the link below to stream and download Alagbara Giga by Bidemi Olaoba.
Lyrics of Alagbara Giga by Bidemi Olaoba
E Jeba
E jekokore o Ope Lonje reOpe L’onje E jeba
E je kokore o Ope L’onje re Eni t‘o ngbe ni bi MimoOpe L’onje
Ope L’onje E jebaOpe L’onje
O ki Je pizza Ope L’onje O ki gbese Ope L’onje O ki Je iti juOpe L’onje E jeba
E je kokore o Ope L’onje reSi iwo Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re A nko, AleluyaSi iwo Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re A nko, AleluyaSi Iwo Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re A nko, AleluyaSi Iwo Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re A nko, AleluyaNo shadow You won’t light up
No shadow You won’t light up Mountain You won’t climb up Coming after meAwon orun bami yin o Pe ese
Awon orun bami yin o Pe ese Awon orun bami yin o Pe ese Awon orun bami yin o Pe ese Jesu Awon orun bami yin o Pe eseWe bless you lord you are holy
And forever you are lordEmi Awon Woli
Baba Agba arugbo
Iwo lo yeOnibu ore
Bawo la ba ti fe o to Onibu oreOba to da orun oun aye
Iwo niyin at’ ope ye fun Bawo la ba ti fe O to Onibu oreOKe nlanla, oke wewe
(Great mountains, small mountains) Iji lile, ko le duro niwaju re (Powerful storms cannot stand before you) Olorun, be ti tobi to o (God, you are so great) E tobi Oluwa (You are great Lord)
Leave a Reply